20 Jese di ẹrù burẹdi ru kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ kan, ati waini tí wọ́n rọ sinu ìgò aláwọ pẹlu ọmọ ewúrẹ́ kan, ó kó wọn rán Dafidi sí Saulu.
Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 16
Wo Samuẹli Kinni 16:20 ni o tọ