Samuẹli Kinni 17:13 BM

13 Àwọn mẹta tí wọ́n dàgbà jùlọ láàrin àwọn ọmọ Jese bá Saulu lọ sójú ogun. Eliabu ni orúkọ àkọ́bí. Abinadabu ni ti ekeji, Ṣama sì ni ti ẹkẹta.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 17

Wo Samuẹli Kinni 17:13 ni o tọ