2 Saulu ati àwọn ọmọ ogun Israẹli pa ibùdó tiwọn sí àfonífojì Ela, wọ́n sì múra ogun de àwọn ọmọ ogun Filistini.
Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 17
Wo Samuẹli Kinni 17:2 ni o tọ