Samuẹli Kinni 17:33 BM

33 Saulu bá sọ fún Dafidi pé, “O kò lè bá Filistini yìí jà, nítorí pé ọmọde ni ọ́, òun sì ti jẹ́ jagunjagun láti ìgbà èwe rẹ̀ wá.”

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 17

Wo Samuẹli Kinni 17:33 ni o tọ