Samuẹli Kinni 18:1 BM

1 Lẹ́yìn tí Dafidi ati Saulu parí ọ̀rọ̀ wọn, ọkàn Jonatani, ọmọ Saulu fà mọ́ Dafidi lọpọlọpọ ó sì fẹ́ràn rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ẹ̀mí ara rẹ̀.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 18

Wo Samuẹli Kinni 18:1 ni o tọ