19 Ṣugbọn nígbà tí ó tó àkókò tí ó yẹ kí Saulu fi Merabu fún Dafidi, Adirieli ará Mehola ni ó fún.
Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 18
Wo Samuẹli Kinni 18:19 ni o tọ