Samuẹli Kinni 18:21 BM

21 Ó wí ninu ara rẹ̀ pé, “N óo fi Mikali fún Dafidi kí ó lè jẹ́ ìdẹkùn fún un, àwọn Filistini yóo sì rí i pa.” Saulu ṣèlérí fún Dafidi lẹẹkeji pé, “O óo di àna mi.”

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 18

Wo Samuẹli Kinni 18:21 ni o tọ