23 Nígbà tí wọ́n sọ èyí fún Dafidi, ó dá wọn lóhùn pé, “Kì í ṣe nǹkan kékeré ni láti jẹ́ àna ọba, talaka ni mí, èmi kì í sì í ṣe eniyan pataki.”
Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 18
Wo Samuẹli Kinni 18:23 ni o tọ