Samuẹli Kinni 19:15 BM

15 Saulu tún rán àwọn iranṣẹ náà lọ wo Dafidi, ó sọ fún wọn pé, “Ẹ gbé e wá fún mi ti òun ti ibùsùn rẹ̀, kí n pa á.”

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 19

Wo Samuẹli Kinni 19:15 ni o tọ