6 Saulu gbọ́rọ̀ sí Jonatani lẹ́nu, ó sì búra ní orúkọ OLUWA pé, “Bí OLUWA ti ń bẹ, n kò ní pa á.”
Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 19
Wo Samuẹli Kinni 19:6 ni o tọ