Samuẹli Kinni 19:8 BM

8 Ogun tún bẹ́ sílẹ̀ láàrin àwọn Filistini ati Israẹli. Dafidi kọlu àwọn Filistini, ó pa pupọ ninu wọn tóbẹ́ẹ̀ tí àwọn Filistini fi sá lójú ogun.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 19

Wo Samuẹli Kinni 19:8 ni o tọ