Samuẹli Kinni 2:11 BM

11 Lẹ́yìn náà, Elikana pada sí ilé rẹ̀ ní Rama. Ṣugbọn Samuẹli dúró sí Ṣilo, ó ń ṣiṣẹ́ iranṣẹ sin OLUWA, lábẹ́ alufaa Eli.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 2

Wo Samuẹli Kinni 2:11 ni o tọ