Samuẹli Kinni 2:20 BM

20 Eli a máa súre fún Elikana ati Hana aya rẹ̀ pé, “OLUWA yóo jẹ́ kí obinrin yìí bí ọmọ mìíràn fún ọ, dípò èyí tí ó yà sọ́tọ̀ fún OLUWA.”Lẹ́yìn náà, wọn yóo pada lọ sí ilé wọn.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 2

Wo Samuẹli Kinni 2:20 ni o tọ