Samuẹli Kinni 2:3 BM

3 Má sọ̀rọ̀ pẹlu ìgbéraga mọ́,má jẹ́ kí ọ̀rọ̀ ìgbéraga ti ẹnu rẹ jáde,nítorí Ọlọrun tí ó mọ ohun gbogbo ni OLUWA,gbogbo ohun tí ẹ̀dá bá ṣe ni ó sì máa ń gbéyẹ̀wò.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 2

Wo Samuẹli Kinni 2:3 ni o tọ