Samuẹli Kinni 2:9 BM

9 “Yóo pa àwọn olóòótọ́ tí wọ́n jẹ́ tirẹ̀ mọ́,ṣugbọn yóo mú kí àwọn eniyan burúkú parẹ́ ninu òkùnkùn;nítorí pé, kì í ṣe nípa agbára eniyan, ni ẹnikẹ́ni lè fi ṣẹgun.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 2

Wo Samuẹli Kinni 2:9 ni o tọ