Samuẹli Kinni 20:22 BM

22 Ṣugbọn bí mo bá sọ fún un pé, ‘Wo àwọn ọfà náà níwájú rẹ,’ máa bá tìrẹ lọ nítorí OLUWA ni ó fẹ́ kí o lọ.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 20

Wo Samuẹli Kinni 20:22 ni o tọ