26 Sibẹ Saulu kò sọ nǹkankan nítorí pé ó rò pé bóyá nǹkankan ti ṣẹlẹ̀ sí Dafidi, tí ó sì sọ ọ́ di aláìmọ́ ni.
Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 20
Wo Samuẹli Kinni 20:26 ni o tọ