33 Saulu bá ju ọ̀kọ̀ rẹ̀ mọ́ ọn, ó fẹ́ pa á. Nígbà náà ni Jonatani mọ̀ dájú pé, baba òun pinnu láti pa Dafidi.
Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 20
Wo Samuẹli Kinni 20:33 ni o tọ