Samuẹli Kinni 20:6 BM

6 Bí baba rẹ bá bèèrè mi, sọ fún un pé mo ti gbààyè lọ́wọ́ rẹ láti lọ sí ìlú mi, ní Bẹtilẹhẹmu, nítorí pé àkókò yìí jẹ́ àkókò fún àjọ̀dún ẹbọ ọdọọdún ìdílé wa.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 20

Wo Samuẹli Kinni 20:6 ni o tọ