Samuẹli Kinni 22:14 BM

14 Ahimeleki dáhùn pé, “Ta ló jẹ́ olóòótọ́ bíi Dafidi láàrin gbogbo àwọn olórí ogun rẹ? Ṣebí àna rẹ ni, ó sì jẹ́ olórí àwọn ọmọ ogun tí wọn ń ṣọ́ ọ ati eniyan pataki ninu ilé rẹ.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 22

Wo Samuẹli Kinni 22:14 ni o tọ