Samuẹli Kinni 22:19 BM

19 Saulu pàṣẹ pé kí wọ́n pa gbogbo àwọn tí wọn ń gbé Nobu, ìlú àwọn alufaa, atọkunrin atobinrin, àtọmọdé, àtọmọ ọwọ́, ati mààlúù, ati kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́, ati aguntan, wọ́n sì pa gbogbo wọn.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 22

Wo Samuẹli Kinni 22:19 ni o tọ