Samuẹli Kinni 22:9 BM

9 Doegi ará Edomu, tí ó dúró láàrin àwọn olórí ogun Saulu dáhùn pé, “Mo rí Dafidi nígbà tí ó lọ sọ́dọ̀ Ahimeleki ọmọ Ahitubu ní Nobu.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 22

Wo Samuẹli Kinni 22:9 ni o tọ