14 Dafidi bá ń lọ gbé orí òkè kan tí ó ṣe é farapamọ́ sí ní aṣálẹ̀ Sifi. Saulu ń wá a lojoojumọ láti pa á, ṣugbọn Ọlọrun kò fi Dafidi lé e lọ́wọ́.
Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 23
Wo Samuẹli Kinni 23:14 ni o tọ