2 ó bèèrè lọ́wọ́ OLUWA pé, “Ṣé kí n gbógun ti àwọn ará Filistia?”OLUWA dáhùn pé, “Gbógun tì wọ́n kí o sì gba àwọn ará Keila sílẹ̀.”
Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 23
Wo Samuẹli Kinni 23:2 ni o tọ