22 Ẹ lọ nisinsinyii kí ẹ sì tún ṣe ìwádìí dáradára nípa ibi tí ó wà, ati ẹni tí ó rí i níbẹ̀; nítorí mo gbọ́ pé alárèékérekè ẹ̀dá ni Dafidi.
Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 23
Wo Samuẹli Kinni 23:22 ni o tọ