24 Wọ́n bá pada sí Sifi ṣáájú Saulu. Ṣugbọn Dafidi ati àwọn ọkunrin rẹ̀ ti wà ní aṣálẹ̀ Maoni tí ó wà ní Araba lápá ìhà gúsù Jeṣimoni.
Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 23
Wo Samuẹli Kinni 23:24 ni o tọ