1 Nígbà tí Saulu bá àwọn ará Filistia jagun tán, wọ́n sọ fún un pé Dafidi wà ní aṣálẹ̀ Engedi.
Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 24
Wo Samuẹli Kinni 24:1 ni o tọ