12 Kí OLUWA dájọ́ láàrin èmi pẹlu rẹ. Kí ó sì jẹ ọ́ níyà fún ìwà burúkú tí ò ń hù sí mi, nítorí pé n kò ní ṣe ọ́ ní ibi kan.
Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 24
Wo Samuẹli Kinni 24:12 ni o tọ