16 Nígbà tí Dafidi parí ọ̀rọ̀ rẹ̀, Saulu dáhùn pé, “Ṣé ohùn rẹ ni mò ń gbọ́, Dafidi ọmọ mi?” Saulu sì bẹ̀rẹ̀ sí sọkún.
Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 24
Wo Samuẹli Kinni 24:16 ni o tọ