7 Nípa báyìí Dafidi dá àwọn eniyan rẹ̀ dúró, kò sì jẹ́ kí wọ́n pa Saulu.Saulu jáde ninu ihò náà, ó bá ọ̀nà rẹ̀ lọ.
Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 24
Wo Samuẹli Kinni 24:7 ni o tọ