Samuẹli Kinni 25:14 BM

14 Ọ̀kan ninu àwọn ọdọmọkunrin Nabali sọ fún Abigaili, iyawo Nabali pé, “Dafidi rán àwọn iranṣẹ láti aṣálẹ̀ wá sọ́dọ̀ oluwa wa, ṣugbọn ó kanra mọ́ wọn.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 25

Wo Samuẹli Kinni 25:14 ni o tọ