Samuẹli Kinni 25:17 BM

17 Jọ̀wọ́ ro ọ̀rọ̀ náà dáradára, kí o sì pinnu ohun tí o bá fẹ́ ṣe; nítorí pé wọ́n ti gbèrò ibi sí oluwa wa ati ìdílé rẹ̀, ọlọ́kàn líle sì ni oluwa wa, ẹnikẹ́ni kò lè bá a sọ̀rọ̀.”

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 25

Wo Samuẹli Kinni 25:17 ni o tọ