Samuẹli Kinni 25:9 BM

9 Nígbà tí àwọn tí Dafidi rán dé ibẹ̀, wọ́n jíṣẹ́ fún Nabali, ní orúkọ Dafidi, wọ́n sì dúró.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 25

Wo Samuẹli Kinni 25:9 ni o tọ