20 Má jẹ́ kí n kú sílẹ̀ àjèjì níbi tí OLUWA kò sí. Kí ló dé tí ọba Israẹli fi ń lépa èmi kékeré yìí, bí ẹni ń dọdẹ àparò lórí òkè?”
Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 26
Wo Samuẹli Kinni 26:20 ni o tọ