24 Gẹ́gẹ́ bí mo ti dá ẹ̀mí rẹ sí lónìí, kí OLUWA ṣe bẹ́ẹ̀ sí mi, kí ó sì yọ mí kúrò ninu gbogbo ìṣòro.”
Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 26
Wo Samuẹli Kinni 26:24 ni o tọ