Samuẹli Kinni 26:3 BM

3 Wọ́n pabùdó wọn sí ẹ̀bá ọ̀nà ní òkè Hakila, Dafidi sì wà ninu aṣálẹ̀ náà. Nígbà tí Dafidi mọ̀ pé Saulu ń wá òun kiri,

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 26

Wo Samuẹli Kinni 26:3 ni o tọ