Samuẹli Kinni 27:9 BM

9 Dafidi pa gbogbo wọn, lọkunrin ati lobinrin, ó sì kó àwọn aguntan, mààlúù, kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ ati ràkúnmí wọn, ati aṣọ wọn, ó sì pada lọ bá Akiṣi.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 27

Wo Samuẹli Kinni 27:9 ni o tọ