Samuẹli Kinni 28:1 BM

1 Nígbà tí ó ṣe, àwọn ará Filistia kó ara wọn jọ láti bá Israẹli jagun. Akiṣi sọ fún Dafidi pé, “Ìwọ ati àwọn ọkunrin tí wọ́n wà pẹlu rẹ yóo jà fún mi.”

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 28

Wo Samuẹli Kinni 28:1 ni o tọ