Samuẹli Kinni 28:18 BM

18 O ṣàìgbọràn sí àṣẹ OLUWA, nítorí pé, o kò pa gbogbo àwọn ará Amaleki ati àwọn nǹkan ìní wọn run. Ìdí nìyí tí OLUWA fi ṣe àwọn nǹkan wọnyi sí ọ lónìí.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 28

Wo Samuẹli Kinni 28:18 ni o tọ