Samuẹli Kinni 28:23 BM

23 Saulu kọ̀, kò fẹ́ jẹun. Ṣugbon àwọn iranṣẹ rẹ̀ ati obinrin náà bẹ̀ ẹ́ kí ó jẹun. Ó gbà, ó dìde nílẹ̀, ó sì jókòó lórí ibùsùn.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 28

Wo Samuẹli Kinni 28:23 ni o tọ