Samuẹli Kinni 28:5 BM

5 Nígbà tí Saulu rí àwọn ọmọ ogun Filistini, àyà rẹ̀ já, ẹ̀rù sì bà á lọpọlọpọ.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 28

Wo Samuẹli Kinni 28:5 ni o tọ