1 Àwọn ará Filistia kó gbogbo àwọn ọmọ ogun wọn jọ sí Afeki, àwọn ọmọ ogun Israẹli sì pa ibùdó sí etí orísun omi tí ó wà ní àfonífojì Jesireeli.
Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 29
Wo Samuẹli Kinni 29:1 ni o tọ