Samuẹli Kinni 29:5 BM

5 Àbí nítorí Dafidi yìí kọ́ ni àwọn ọmọbinrin Israẹli ṣe ń jó tí wọ́n sì ń kọrin pé,‘Saulu pa ẹgbẹẹgbẹrun tirẹ̀,ṣugbọn Dafidi pa ẹgbẹẹgbaarun tirẹ̀?’ ”

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 29

Wo Samuẹli Kinni 29:5 ni o tọ