9 Akiṣi sì dáhùn pé, “Nítòótọ́ ni, mo mọ̀ pé o jẹ́ ẹni rere bí angẹli OLUWA, ṣugbọn àwọn olórí ogun ti sọ pé, o kò lè bá wa lọ sójú ogun.
Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 29
Wo Samuẹli Kinni 29:9 ni o tọ