21 OLUWA tún fi ara hàn ní Ṣilo, nítorí pé níbẹ̀ ni ó ti kọ́ fi ara han Samuẹli, tí ó sì bá a sọ̀rọ̀.
Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 3
Wo Samuẹli Kinni 3:21 ni o tọ