16 Ó mú Dafidi lọ bá wọn.Àwọn ọmọ ogun náà fọ́n káàkiri, wọ́n ń jẹ, wọ́n ń mu, wọ́n sì ń jó, nítorí ọpọlọpọ ìkógun tí wọ́n rí kó ní ilẹ̀ àwọn ará Filistia ati Juda.
Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 30
Wo Samuẹli Kinni 30:16 ni o tọ