Samuẹli Kinni 30:22 BM

22 Àwọn tí wọ́n jẹ́ eniyan burúkú ati òǹrorò láàrin àwọn tí wọ́n bá Dafidi lọ ní, “Nítorí pé wọn kò bá wa lọ, a kò ní fún wọn ninu ìkógun wa tí a gbà pada, àfi aya ati àwọn ọmọ wọn nìkan ni wọ́n lè gbà.”

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 30

Wo Samuẹli Kinni 30:22 ni o tọ