24 Kò sí ẹni tí yóo fara mọ́ àbá yín yìí. Gbogbo wa ni a óo jọ pín ìkógun náà dọ́gba-dọ́gba, ati àwọn tí ó lọ ati àwọn tí ó dúró ti ẹrù.”
Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 30
Wo Samuẹli Kinni 30:24 ni o tọ