Samuẹli Kinni 30:3 BM

3 Nígbà tí Dafidi ati àwọn ọmọlẹ́yìn rẹ̀ dé, wọ́n rí i pé wọ́n ti dáná sun ìlú náà, wọ́n sì ti kó àwọn aya wọn ati àwọn ọmọ wọn lọkunrin ati lobinrin lẹ́rú.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 30

Wo Samuẹli Kinni 30:3 ni o tọ