5 Wọ́n kó àwọn aya Dafidi mejeeji, Ahinoamu ará Jesireeli ati Abigaili opó Nabali lẹ́rú pẹlu.
Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 30
Wo Samuẹli Kinni 30:5 ni o tọ